Sáàmù 130:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jáà,* tó bá jẹ́ pé àṣìṣe lò ń wò,*Jèhófà, ta ló lè dúró?+ Sáàmù 143:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Má ṣe bá ìránṣẹ́ rẹ ṣẹjọ́,Nítorí kò sí alààyè kankan tó lè jẹ́ olódodo níwájú rẹ.+