ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nehemáyà 10:28-30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Ìyókù àwọn èèyàn náà, ìyẹn àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì, àwọn aṣọ́bodè, àwọn akọrin, àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* àti gbogbo àwọn tó ya ara wọn sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn èèyàn ilẹ̀ tó yí wọn ká kí wọ́n lè pa Òfin Ọlọ́run tòótọ́ mọ́,+ pẹ̀lú àwọn ìyàwó wọn, àwọn ọmọkùnrin wọn àti àwọn ọmọbìnrin wọn, gbogbo àwọn tó ní ìmọ̀ àti òye,* 29 dara pọ̀ mọ́ àwọn arákùnrin wọn, àwọn olókìkí àárín wọn, wọ́n gégùn-ún, wọ́n sì búra pé wọ́n á máa rìn nínú Òfin Ọlọ́run tòótọ́, èyí tó wá nípasẹ̀ Mósè ìránṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́ àti pé àwọn á rí i pé àwọn ń pa gbogbo àṣẹ Jèhófà Olúwa wa mọ́ àti àwọn ìdájọ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ìlànà rẹ̀. 30 A kò ní fi àwọn ọmọbìnrin wa fún àwọn èèyàn ilẹ̀ náà, a kò sì ní fẹ́ àwọn ọmọbìnrin wọn fún àwọn ọmọkùnrin wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́