-
Ẹ́sírà 10:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ṣùgbọ́n àwọn tó wà nígbèkùn tẹ́lẹ̀ ṣe ohun tí wọ́n fẹnu kò sí; àlùfáà Ẹ́sírà àti àwọn olórí ìdílé nínú àwọn agbo ilé bàbá wọn, tí orúkọ wọn wà lákọsílẹ̀, kóra jọ lọ́tọ̀ ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá láti bójú tó ọ̀rọ̀ náà; 17 nígbà tó di ọjọ́ kìíní oṣù kìíní, wọ́n yanjú ọ̀rọ̀ gbogbo àwọn ọkùnrin tó fẹ́ àwọn obìnrin àjèjì.
-