Nehemáyà 7:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Àwọn akọrin nìyí:+ àwọn ọmọ Ásáfù,+ wọ́n jẹ́ méjìdínláàádọ́jọ (148).