-
1 Kíróníkà 24:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Dáfídì àti Sádókù+ látinú àwọn ọmọ Élíásárì àti Áhímélékì látinú àwọn ọmọ Ítámárì pín wọn sí àwùjọ-àwùjọ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ìsìn wọn.
-
-
1 Kíróníkà 24:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 ìkeje fún Hákósì, ìkẹjọ fún Ábíjà,+
-
-
Nehemáyà 3:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Lẹ́yìn rẹ̀, Mérémótì+ ọmọ Úríjà ọmọ Hákósì tún ẹ̀ka míì ṣe, láti ẹnu ọ̀nà ilé Élíáṣíbù títí dé òpin ilé Élíáṣíbù.
-