Hágáì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ní ọdún kejì tí Ọba Dáríúsì ń ṣàkóso, ní oṣù kẹfà, ní ọjọ́ kìíní oṣù náà, Jèhófà rán wòlíì Hágáì*+ pé kó sọ fún Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì, gómìnà Júdà àti Jóṣúà ọmọ Jèhósádákì, àlùfáà àgbà pé:
1 Ní ọdún kejì tí Ọba Dáríúsì ń ṣàkóso, ní oṣù kẹfà, ní ọjọ́ kìíní oṣù náà, Jèhófà rán wòlíì Hágáì*+ pé kó sọ fún Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì, gómìnà Júdà àti Jóṣúà ọmọ Jèhósádákì, àlùfáà àgbà pé: