Ẹ́kísódù 20:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Fi erùpẹ̀ mọ pẹpẹ fún mi, kí o sì rú àwọn ẹbọ sísun rẹ lórí rẹ̀, pẹ̀lú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀* rẹ, agbo ẹran rẹ àti ọ̀wọ́ ẹran rẹ. Gbogbo ibi tí mo bá ti mú kí wọ́n rántí orúkọ mi+ ni màá ti wá bá ọ, tí màá sì bù kún ọ. Ẹ́kísódù 40:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó gbé pẹpẹ ẹbọ sísun+ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ ìpàdé náà, kó lè fi ẹbọ sísun+ àti ọrẹ ọkà rúbọ lórí rẹ̀, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.
24 Fi erùpẹ̀ mọ pẹpẹ fún mi, kí o sì rú àwọn ẹbọ sísun rẹ lórí rẹ̀, pẹ̀lú àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀* rẹ, agbo ẹran rẹ àti ọ̀wọ́ ẹran rẹ. Gbogbo ibi tí mo bá ti mú kí wọ́n rántí orúkọ mi+ ni màá ti wá bá ọ, tí màá sì bù kún ọ.
29 Ó gbé pẹpẹ ẹbọ sísun+ sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ ìpàdé náà, kó lè fi ẹbọ sísun+ àti ọrẹ ọkà rúbọ lórí rẹ̀, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.