Sekaráyà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Serubábélì ló fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe ìpìlẹ̀ ilé yìí,+ ọwọ́ rẹ̀ náà ni yóò sì parí rẹ̀.+ Ẹ ó sì mọ̀ pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló rán mi sí yín.
9 “Serubábélì ló fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe ìpìlẹ̀ ilé yìí,+ ọwọ́ rẹ̀ náà ni yóò sì parí rẹ̀.+ Ẹ ó sì mọ̀ pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló rán mi sí yín.