-
Nọ́ńbà 10:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àwọn ọmọ Áárónì, àwọn àlùfáà, ni kó máa fun àwọn kàkàkí+ náà. Kí ẹ máa lò ó, kó jẹ́ àṣẹ tó máa wà títí lọ fún yín jálẹ̀ àwọn ìran yín.
-