Nehemáyà 6:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Gbogbo wọn ló fẹ́ máa dẹ́rù bà wá, wọ́n ń sọ pé: “Wọ́n á dẹwọ́ lẹ́nu iṣẹ́ náà, wọn ò sì ní parí rẹ̀.”+ Ní báyìí, mo gbàdúrà, jọ̀wọ́ fún mi lókun.+
9 Gbogbo wọn ló fẹ́ máa dẹ́rù bà wá, wọ́n ń sọ pé: “Wọ́n á dẹwọ́ lẹ́nu iṣẹ́ náà, wọn ò sì ní parí rẹ̀.”+ Ní báyìí, mo gbàdúrà, jọ̀wọ́ fún mi lókun.+