ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 18:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ní ọdún kẹta Hóṣéà+ ọmọ Élà ọba Ísírẹ́lì, Hẹsikáyà+ ọmọ Áhásì+ ọba Júdà di ọba.

  • 2 Àwọn Ọba 18:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Jèhófà sì wà pẹ̀lú rẹ̀. Ó ń hùwà ọgbọ́n níbikíbi tó bá lọ. Ó ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Ásíríà, ó sì kọ̀ láti sìn ín.+

  • 2 Àwọn Ọba 24:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ìbínú Jèhófà ló mú kí àwọn nǹkan yìí ṣẹlẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù àti ní Júdà, títí ó fi gbá wọn dà nù kúrò níwájú rẹ̀.+ Sedekáyà sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Bábílónì.+

  • Ẹ́sírà 4:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 kí o lè wádìí nínú àkọsílẹ̀ àwọn baba ńlá rẹ.+ Wàá rí i nínú àkọsílẹ̀ pé ìlú yẹn jẹ́ ìlú ọ̀tẹ̀, ó máa ń pa àwọn ọba àti àwọn ìpínlẹ̀* lára, ó sì ti pẹ́ tí àwọn tó wà nínú rẹ̀ ti máa ń dìtẹ̀. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi pa ìlú náà run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́