1 Kíróníkà 9:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn aṣọ́bodè+ ni Ṣálúmù, Ákúbù, Tálímónì, Áhímánì àti Ṣálúmù arákùnrin wọn tó jẹ́ olórí, 18 títí di ìgbà náà, ẹnubodè ọba lápá ìlà oòrùn+ ni ó wà. Àwọn ni aṣọ́bodè ibùdó àwọn ọmọ Léfì.
17 Àwọn aṣọ́bodè+ ni Ṣálúmù, Ákúbù, Tálímónì, Áhímánì àti Ṣálúmù arákùnrin wọn tó jẹ́ olórí, 18 títí di ìgbà náà, ẹnubodè ọba lápá ìlà oòrùn+ ni ó wà. Àwọn ni aṣọ́bodè ibùdó àwọn ọmọ Léfì.