-
Nehemáyà 4:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Síbẹ̀, àwọn èèyàn Júdà ń sọ pé: “Àwọn lébìrà* ò lágbára mọ́, àwókù tó wà nílẹ̀ sì pọ̀ gan-an; a ò lè mọ ògiri náà láé.”