-
Nọ́ńbà 10:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “Tí ẹ bá lọ bá ọ̀tá tó ń ni yín lára jagun ní ilẹ̀ yín, ẹ fi àwọn kàkàkí+ náà kéde ogun, Jèhófà Ọlọ́run yín yóò sì rántí yín, yóò gbà yín lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá yín.
-
-
2 Kíróníkà 13:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ẹ wò ó! Ọlọ́run tòótọ́ wà pẹ̀lú wa, ó ń darí wa. Àwọn àlùfáà rẹ̀ sì wà níbí láti máa fun kàkàkí láti fi pe ogun sí yín. Ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ má ṣe bá Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá yín jà, torí ẹ ò ní ṣàṣeyọrí.”+
-