Léfítíkù 25:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Má gba èlé tàbí kí o jèrè lára rẹ̀.*+ Kí o máa bẹ̀rù Ọlọ́run rẹ,+ arákùnrin rẹ yóò sì máa wà láàyè pẹ̀lú rẹ. Nehemáyà 5:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́, àwọn gómìnà tó wà ṣáájú mi ti di ẹrù tó wúwo sórí àwọn èèyàn náà, wọ́n sì ń gba ogójì (40) ṣékélì* fàdákà lọ́wọ́ wọn fún oúnjẹ àti wáìnì lójoojúmọ́. Àwọn ìránṣẹ́ wọn tún ń ni àwọn èèyàn lára. Ṣùgbọ́n mi ò ṣe bẹ́ẹ̀+ nítorí ìbẹ̀rù Ọlọ́run.+
36 Má gba èlé tàbí kí o jèrè lára rẹ̀.*+ Kí o máa bẹ̀rù Ọlọ́run rẹ,+ arákùnrin rẹ yóò sì máa wà láàyè pẹ̀lú rẹ.
15 Àmọ́, àwọn gómìnà tó wà ṣáájú mi ti di ẹrù tó wúwo sórí àwọn èèyàn náà, wọ́n sì ń gba ogójì (40) ṣékélì* fàdákà lọ́wọ́ wọn fún oúnjẹ àti wáìnì lójoojúmọ́. Àwọn ìránṣẹ́ wọn tún ń ni àwọn èèyàn lára. Ṣùgbọ́n mi ò ṣe bẹ́ẹ̀+ nítorí ìbẹ̀rù Ọlọ́run.+