-
Nehemáyà 5:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Àwọn míì ń sọ pé: “Àwọn oko wa àti àwọn ọgbà àjàrà wa pẹ̀lú àwọn ilé wa la fi ṣe ohun ìdúró, ká lè rí ọkà lásìkò tí kò sí oúnjẹ.”
-