-
Ìṣe 20:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Fàdákà tàbí wúrà tàbí aṣọ èèyàn kankan ò wọ̀ mí lójú.+
-
-
2 Kọ́ríńtì 12:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Mi ò fi ìkankan nínú àwọn tí mo rán sí yín yàn yín jẹ, àbí mo ṣe bẹ́ẹ̀?
-