3 Lásìkò náà, Tòbáyà+ ọmọ Ámónì+ tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ sọ pé: “Kódà tí kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ bá gun ohun tí wọ́n ń kọ́, ó máa wó ògiri olókùúta wọn lulẹ̀.”
4 Gbọ́, ìwọ Ọlọ́run wa, nítorí wọ́n ń kàn wá lábùkù,+ dá ẹ̀gàn wọn pa dà sórí wọn,+ jẹ́ kí wọ́n dà bí ẹrù ogun, kí wọ́n sì di ẹrú ní ilẹ̀ àjèjì.