Nehemáyà 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Apá tó tẹ̀ lé tiwọn ni Mérémótì + ọmọ Úríjà ọmọ Hákósì ti ṣe iṣẹ́ àtúnṣe, Méṣúlámù+ ọmọ Berekáyà ọmọ Meṣesábélì sì ṣe iṣẹ́ àtúnṣe ní apá tó tẹ̀ lé tiwọn, bákan náà Sádókù ọmọ Béánà ṣe iṣẹ́ àtúnṣe ní apá tó tẹ̀ lé tiwọn.
4 Apá tó tẹ̀ lé tiwọn ni Mérémótì + ọmọ Úríjà ọmọ Hákósì ti ṣe iṣẹ́ àtúnṣe, Méṣúlámù+ ọmọ Berekáyà ọmọ Meṣesábélì sì ṣe iṣẹ́ àtúnṣe ní apá tó tẹ̀ lé tiwọn, bákan náà Sádókù ọmọ Béánà ṣe iṣẹ́ àtúnṣe ní apá tó tẹ̀ lé tiwọn.