-
Nehemáyà 6:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Mo wá lọ sí ilé Ṣemáyà ọmọ Deláyà ọmọ Méhétábélì nígbà tó wà ní àhámọ́ níbẹ̀. Ó sọ fún mi pé: “Jẹ́ ká dá ìgbà tí a jọ máa pàdé ní ilé Ọlọ́run tòótọ́, nínú tẹ́ńpìlì, ká sì ti àwọn ilẹ̀kùn tẹ́ńpìlì, nítorí wọ́n ń bọ̀ wá pa ọ́. Òru ni wọ́n máa wá pa ọ́.”
-
-
Nehemáyà 6:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ńṣe ni wọ́n gbà á kó lè dẹ́rù bà mí, kí n sì dẹ́ṣẹ̀, kí wọ́n lè rí ẹ̀sùn tí wọ́n á fi bà mí lórúkọ jẹ́, kí wọ́n sì fi mí ṣẹ̀sín.
-