-
Léfítíkù 25:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Torí ẹrú mi tí mo mú kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì ni wọ́n.+ Kí wọ́n má ta ara wọn bí ẹni ta ẹrú.
-
-
Diutarónómì 5:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Rántí pé o di ẹrú ní ilẹ̀ Íjíbítì àti pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ fi ọwọ́ agbára àti apá rẹ̀ tó nà jáde mú ọ kúrò níbẹ̀.+ Ìdí nìyẹn tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fi pàṣẹ fún ọ pé kí o máa pa ọjọ́ Sábáàtì mọ́.
-