Nehemáyà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Lákòókò náà, Hánáánì,+ ọ̀kan lára àwọn arákùnrin mi pẹ̀lú àwọn ọkùnrin míì láti Júdà wá sọ́dọ̀ mi, mo sì béèrè lọ́wọ́ wọn nípa àwọn Júù tó ṣẹ́ kù, tí wọ́n yè bọ́ lóko ẹrú,+ mo tún béèrè nípa Jerúsálẹ́mù.
2 Lákòókò náà, Hánáánì,+ ọ̀kan lára àwọn arákùnrin mi pẹ̀lú àwọn ọkùnrin míì láti Júdà wá sọ́dọ̀ mi, mo sì béèrè lọ́wọ́ wọn nípa àwọn Júù tó ṣẹ́ kù, tí wọ́n yè bọ́ lóko ẹrú,+ mo tún béèrè nípa Jerúsálẹ́mù.