-
1 Kíróníkà 9:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Orúkọ gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wà nínú àkọsílẹ̀ ìdílé wọn, a sì kọ wọ́n sínú Ìwé Àwọn Ọba Ísírẹ́lì. Àwọn ọmọ Júdà ni a sì kó lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì nítorí ìwà àìṣòótọ́+ wọn.
-
-
Ẹ́sírà 2:59Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
59 Àwọn tó lọ láti Tẹli-mélà, Tẹli-háṣà, Kérúbù, Ádónì àti Ímérì, àmọ́ tí wọn kò lè sọ agbo ilé bàbá wọn àti ibi tí wọ́n ti ṣẹ̀ wá láti fi hàn pé ọmọ Ísírẹ́lì ni wọ́n nìyí:+
-