ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 8:49, 50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 49 nígbà náà, láti ibi tí ò ń gbé ní ọ̀run,+ kí o gbọ́ àdúrà wọn àti ẹ̀bẹ̀ wọn pé kí o ṣojú rere sí àwọn, kí o sì ṣe ìdájọ́ nítorí wọn, 50 kí o dárí ji àwọn èèyàn rẹ tó ṣẹ̀ ọ́, kí o dárí gbogbo bí wọ́n ṣe tẹ ìlànà rẹ lójú jì wọ́n. Kí o jẹ́ kí wọ́n rójú àánú àwọn tó kó wọn lẹ́rú, kí wọ́n sì ṣàánú wọn+

  • Ẹ́sírà 7:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ẹ́sírà yìí dé láti Bábílónì. Ó jẹ́ adàwékọ* tó mọ Òfin Mósè+ dunjú,* èyí tó wá látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì. Gbogbo ohun tó béèrè ni ọba fún un, nítorí ọwọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ wà lára rẹ̀.

  • Sáàmù 106:46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Á jẹ́ kí àánú wọn máa ṣe

      Gbogbo àwọn tó mú wọn lẹ́rú.+

  • Òwe 21:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ọkàn ọba dà bí odò ní ọwọ́ Jèhófà.+

      Ibi tí Ó bá fẹ́ ló ń darí rẹ̀ sí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́