1 Sámúẹ́lì 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn Filísínì pẹ̀lú kóra jọ láti bá Ísírẹ́lì jà, wọ́n ní ọ̀kẹ́ kan ààbọ̀ (30,000) kẹ̀kẹ́ ogun àti ẹgbẹ̀rún mẹ́fà (6,000) agẹṣin àti àwọn ọmọ ogun tó pọ̀ bí iyanrìn etí òkun;+ wọ́n jáde lọ, wọ́n sì tẹ̀ dó sí Míkímáṣì ní ìlà oòrùn Bẹti-áfénì.+
5 Àwọn Filísínì pẹ̀lú kóra jọ láti bá Ísírẹ́lì jà, wọ́n ní ọ̀kẹ́ kan ààbọ̀ (30,000) kẹ̀kẹ́ ogun àti ẹgbẹ̀rún mẹ́fà (6,000) agẹṣin àti àwọn ọmọ ogun tó pọ̀ bí iyanrìn etí òkun;+ wọ́n jáde lọ, wọ́n sì tẹ̀ dó sí Míkímáṣì ní ìlà oòrùn Bẹti-áfénì.+