Nehemáyà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọ̀rọ̀ Nehemáyà*+ ọmọ Hakaláyà nìyí: Ní oṣù Kísíléfì,* ní ogún ọdún ìṣàkóso ọba,* mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.*
1 Ọ̀rọ̀ Nehemáyà*+ ọmọ Hakaláyà nìyí: Ní oṣù Kísíléfì,* ní ogún ọdún ìṣàkóso ọba,* mo wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá.*