Ẹ́sírà 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Lẹ́yìn àwọn nǹkan yìí, nígbà ìjọba Atasásítà+ ọba Páṣíà, Ẹ́sírà*+ pa dà. Ẹ́sírà jẹ́ ọmọ Seráyà,+ ọmọ Asaráyà, ọmọ Hilikáyà,+ Nehemáyà 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní gbogbo àkókò yìí, mi ò sí ní Jerúsálẹ́mù, nítorí mo lọ sọ́dọ̀ ọba ní ọdún kejìlélọ́gbọ̀n+ Atasásítà+ ọba Bábílónì; lẹ́yìn ìgbà yẹn, mo gba àyè kúrò lẹ́nu iṣẹ́ lọ́dọ̀ ọba.
7 Lẹ́yìn àwọn nǹkan yìí, nígbà ìjọba Atasásítà+ ọba Páṣíà, Ẹ́sírà*+ pa dà. Ẹ́sírà jẹ́ ọmọ Seráyà,+ ọmọ Asaráyà, ọmọ Hilikáyà,+
6 Ní gbogbo àkókò yìí, mi ò sí ní Jerúsálẹ́mù, nítorí mo lọ sọ́dọ̀ ọba ní ọdún kejìlélọ́gbọ̀n+ Atasásítà+ ọba Bábílónì; lẹ́yìn ìgbà yẹn, mo gba àyè kúrò lẹ́nu iṣẹ́ lọ́dọ̀ ọba.