Ẹ́kísódù 15:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Míríámù fi orin dá àwọn ọkùnrin lóhùn pé: “Ẹ kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+ Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.”+ 1 Sámúẹ́lì 18:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nígbà tí Dáfídì àti àwọn tó kù ń pa dà láti ibi tí wọ́n ti lọ pa àwọn Filísínì, àwọn obìnrin jáde látinú gbogbo ìlú Ísírẹ́lì láti fi orin+ àti ijó pàdé Ọba Sọ́ọ̀lù, wọ́n ń lu ìlù tanboríìnì,+ wọ́n sì ń ta gòjé tìdùnnútìdùnnú.
21 Míríámù fi orin dá àwọn ọkùnrin lóhùn pé: “Ẹ kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+ Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.”+
6 Nígbà tí Dáfídì àti àwọn tó kù ń pa dà láti ibi tí wọ́n ti lọ pa àwọn Filísínì, àwọn obìnrin jáde látinú gbogbo ìlú Ísírẹ́lì láti fi orin+ àti ijó pàdé Ọba Sọ́ọ̀lù, wọ́n ń lu ìlù tanboríìnì,+ wọ́n sì ń ta gòjé tìdùnnútìdùnnú.