Nehemáyà 9:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jéṣúà, Bánì, Kádímíélì, Ṣebanáyà, Búnì, Ṣerebáyà,+ Bánì àti Kénánì dúró lórí pèpéle+ àwọn ọmọ Léfì, wọ́n gbé ohùn wọn sókè, wọ́n sì ń sunkún sí Jèhófà Ọlọ́run wọn.
4 Jéṣúà, Bánì, Kádímíélì, Ṣebanáyà, Búnì, Ṣerebáyà,+ Bánì àti Kénánì dúró lórí pèpéle+ àwọn ọmọ Léfì, wọ́n gbé ohùn wọn sókè, wọ́n sì ń sunkún sí Jèhófà Ọlọ́run wọn.