30 Fílípì sáré lọ sí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, ó sì gbọ́ tí ó ń ka ìwé wòlíì Àìsáyà sókè, ó wá bi í pé: “Ǹjẹ́ o tiẹ̀ lóye ohun tí ò ń kà?” 31 Ó dáhùn pé: “Báwo ni mo ṣe lè lóye, láìjẹ́ pé ẹnì kan tọ́ mi sọ́nà?” Torí náà, ó rọ Fílípì pé kó gòkè, kó sì jókòó pẹ̀lú òun.