-
1 Sámúẹ́lì 1:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Hánà ń gbàdúrà nínú ọkàn rẹ̀, ètè rẹ̀ nìkan ló ń mì, a kò sì gbọ́ ohùn rẹ̀. Torí náà, Élì rò pé ó mutí yó ni.