ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 7:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ni Jóṣúà bá fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì wólẹ̀ níwájú Àpótí Jèhófà títí di ìrọ̀lẹ́, òun àti àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì, wọ́n sì ń da iyẹ̀pẹ̀ sí orí ara wọn.

  • Jónà 3:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Àwọn ará ìlú Nínéfè wá gba Ọlọ́run gbọ́,+ wọ́n kéde pé kí gbogbo ìlú gbààwẹ̀, wọ́n sì wọ aṣọ ọ̀fọ̀,* látorí ẹni tó tóbi jù dórí ẹni tó kéré jù. 6 Nígbà tí ọba Nínéfè gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, ó dìde lórí ìtẹ́ rẹ̀, ó bọ́ aṣọ oyè rẹ̀, ó sì wọ aṣọ ọ̀fọ̀, ó sì jókòó sínú eérú.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́