Ẹ́kísódù 16:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Màá rọ̀jò oúnjẹ fún yín láti ọ̀run,+ kí kálukú máa jáde lọ kó iye tó máa tó o lójoojúmọ́,+ kí n lè dán wọn wò, kí n sì rí i bóyá wọ́n á pa òfin mi mọ́ tàbí wọn ò ní pa á mọ́.+
4 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Màá rọ̀jò oúnjẹ fún yín láti ọ̀run,+ kí kálukú máa jáde lọ kó iye tó máa tó o lójoojúmọ́,+ kí n lè dán wọn wò, kí n sì rí i bóyá wọ́n á pa òfin mi mọ́ tàbí wọn ò ní pa á mọ́.+