Diutarónómì 9:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí náà, mọ̀ pé kì í ṣe torí òdodo rẹ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe máa fún ọ ní ilẹ̀ dáradára yìí kí o lè gbà á, torí alágídí* ni ọ́.+
6 Torí náà, mọ̀ pé kì í ṣe torí òdodo rẹ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe máa fún ọ ní ilẹ̀ dáradára yìí kí o lè gbà á, torí alágídí* ni ọ́.+