Nọ́ńbà 14:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Jọ̀ọ́, ro ti ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ tó pọ̀ gan-an, kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn yìí jì wọ́n, bí o ṣe ń dárí jì wọ́n láti Íjíbítì títí di báyìí.”+ 20 Jèhófà wá sọ pé: “Mo dárí jì wọ́n bí o ṣe sọ.+
19 Jọ̀ọ́, ro ti ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ tó pọ̀ gan-an, kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn yìí jì wọ́n, bí o ṣe ń dárí jì wọ́n láti Íjíbítì títí di báyìí.”+ 20 Jèhófà wá sọ pé: “Mo dárí jì wọ́n bí o ṣe sọ.+