-
Nọ́ńbà 20:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 “Mú ọ̀pá, kí ìwọ àti Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ sì pe àwọn èèyàn náà jọ, kí ẹ sì bá àpáta sọ̀rọ̀ níṣojú wọn kí omi lè jáde nínú rẹ̀, kí o fún wọn ní omi látinú àpáta náà, kí o sì fún àpéjọ náà àti ẹran ọ̀sìn wọn ní ohun tí wọ́n máa mu.”+
-