2 Àwọn Ọba 21:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Mánásè ọba Júdà ṣe gbogbo àwọn ohun ìríra yìí; ó ṣe ohun tó burú ju ti gbogbo àwọn Ámórì+ tó wà ṣáájú rẹ̀,+ ó sì fi àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* rẹ̀ mú Júdà dẹ́ṣẹ̀. Sáàmù 106:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀.
11 “Mánásè ọba Júdà ṣe gbogbo àwọn ohun ìríra yìí; ó ṣe ohun tó burú ju ti gbogbo àwọn Ámórì+ tó wà ṣáájú rẹ̀,+ ó sì fi àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* rẹ̀ mú Júdà dẹ́ṣẹ̀.
38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀.