ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 4:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àmọ́ lẹ́yìn tí Éhúdù kú, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà.+ 2 Torí náà, Jèhófà fi wọ́n lé ọwọ́ Jábínì ọba Kénáánì,+ tó jọba ní Hásórì. Sísérà ni olórí àwọn ọmọ ogun rẹ̀, ó sì ń gbé ní Háróṣétì+ ti àwọn orílẹ̀-èdè.*

  • Àwọn Onídàájọ́ 6:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tún ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà,+ torí náà Jèhófà fi wọ́n lé Mídíánì lọ́wọ́ fún ọdún méje.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́