43 Ọ̀pọ̀ ìgbà ló gbà wọ́n sílẹ̀,+
Àmọ́ wọ́n á ṣọ̀tẹ̀, wọ́n á sì ṣàìgbọràn,+
A ó sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀ nítorí àṣìṣe wọn.+
44 Àmọ́ á tún rí ìdààmú tó bá wọn,+
Á sì gbọ́ igbe ìrànlọ́wọ́ wọn.+
45 Nítorí wọn, á rántí májẹ̀mú rẹ̀,
Àánú á sì ṣe é nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tó ga tí kì í sì í yẹ̀.+