-
Ìsíkíẹ́lì 14:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àmọ́ àwọn kan tó ṣẹ́ kù nínú rẹ̀ yóò yè bọ́, wọ́n á sì mú wọn jáde,+ àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin. Wọ́n ń bọ̀ wá sọ́dọ̀ yín, tí ẹ bá sì rí ìwà àti ìṣe wọn, àjálù tí mo mú wá sórí Jerúsálẹ́mù àti gbogbo ohun tí mo ṣe sí i máa tù yín nínú.’”
-