Diutarónómì 28:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 torí o ò fi ìdùnnú àti ayọ̀ tó wá látọkàn sin Jèhófà Ọlọ́run rẹ nígbà tí o ní ohun gbogbo ní ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ.+ Diutarónómì 32:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá. O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+ Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀.
47 torí o ò fi ìdùnnú àti ayọ̀ tó wá látọkàn sin Jèhófà Ọlọ́run rẹ nígbà tí o ní ohun gbogbo ní ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ.+
15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá. O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+ Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀.