Nehemáyà 9:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 “Pẹ̀lú gbogbo èyí, a wọnú àdéhùn kan, a sì kọ àdéhùn+ náà sílẹ̀, àwọn ìjòyè wa, àwọn ọmọ Léfì wa àti àwọn àlùfáà wa ti fọwọ́ sí i, wọ́n sì gbé èdìdì lé e.”+
38 “Pẹ̀lú gbogbo èyí, a wọnú àdéhùn kan, a sì kọ àdéhùn+ náà sílẹ̀, àwọn ìjòyè wa, àwọn ọmọ Léfì wa àti àwọn àlùfáà wa ti fọwọ́ sí i, wọ́n sì gbé èdìdì lé e.”+