Ẹ́sírà 2:58 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 58 Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* àti ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ó lé àádọ́rùn-ún àti méjì (392).
58 Gbogbo àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì* àti ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì jẹ́ ọgọ́rùn-ún mẹ́ta ó lé àádọ́rùn-ún àti méjì (392).