ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 10:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ní báyìí, jọ̀wọ́, jẹ́ kí àwọn olórí wa ṣojú fún gbogbo ìjọ yìí;+ kí gbogbo àwọn tó wà nínú àwọn ìlú wa tí wọ́n ti fẹ́ àwọn aya àjèjì sì jáde wá ní àkókò tí a dá pẹ̀lú àwọn àgbààgbà àti àwọn onídàájọ́ ìlú kọ̀ọ̀kan, títí a ó fi yí ìbínú Ọlọ́run wa tó ń jó bí iná kúrò lórí wa, nítorí ọ̀ràn yìí.”

      15 Àmọ́, Jónátánì ọmọ Ásáhélì àti Jaseáyà ọmọ Tíkífà ta ko ọ̀rọ̀ yìí, Méṣúlámù àti Ṣábétáì+ tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì sì tì wọ́n lẹ́yìn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́