Jóṣúà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé. Jóṣúà 15:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ní Ṣẹ́fẹ́là,+ àwọn ìlú náà ni: Éṣítáólì, Sórà,+ Áṣínà, Jóṣúà 19:40, 41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Kèké keje+ mú ẹ̀yà Dánì+ ní ìdílé-ìdílé. 41 Ààlà ogún wọn sì ni Sórà,+ Éṣítáólì, Iri-ṣéméṣì,