1 Sámúẹ́lì 21:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nígbà tó yá, Dáfídì wá sọ́dọ̀ àlùfáà Áhímélékì ní Nóbù.+ Jìnnìjìnnì bá Áhímélékì nígbà tó pàdé Dáfídì, ó sì sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi dá wá, tí kò sẹ́ni tó tẹ̀ lé ọ?”+
21 Nígbà tó yá, Dáfídì wá sọ́dọ̀ àlùfáà Áhímélékì ní Nóbù.+ Jìnnìjìnnì bá Áhímélékì nígbà tó pàdé Dáfídì, ó sì sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi dá wá, tí kò sẹ́ni tó tẹ̀ lé ọ?”+