Ẹ́sírà 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Lẹ́yìn àwọn nǹkan yìí, nígbà ìjọba Atasásítà+ ọba Páṣíà, Ẹ́sírà*+ pa dà. Ẹ́sírà jẹ́ ọmọ Seráyà,+ ọmọ Asaráyà, ọmọ Hilikáyà,+ Ẹ́sírà 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ́sírà yìí dé láti Bábílónì. Ó jẹ́ adàwékọ* tó mọ Òfin Mósè+ dunjú,* èyí tó wá látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì. Gbogbo ohun tó béèrè ni ọba fún un, nítorí ọwọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ wà lára rẹ̀.
7 Lẹ́yìn àwọn nǹkan yìí, nígbà ìjọba Atasásítà+ ọba Páṣíà, Ẹ́sírà*+ pa dà. Ẹ́sírà jẹ́ ọmọ Seráyà,+ ọmọ Asaráyà, ọmọ Hilikáyà,+
6 Ẹ́sírà yìí dé láti Bábílónì. Ó jẹ́ adàwékọ* tó mọ Òfin Mósè+ dunjú,* èyí tó wá látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì. Gbogbo ohun tó béèrè ni ọba fún un, nítorí ọwọ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ wà lára rẹ̀.