Jóṣúà 15:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ààlà náà tún dé Débírì ní Àfonífojì* Ákórì,+ ó sì yí gba apá àríwá lọ sí Gílígálì,+ tó wà níwájú ibi tí wọ́n ń gbà gòkè ní Ádúmímù, ní gúúsù àfonífojì, ààlà náà dé ibi omi Ẹ́ń-ṣímẹ́ṣì,+ ó sì parí sí Ẹ́ń-rógélì.+ Jóṣúà 15:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.
7 Ààlà náà tún dé Débírì ní Àfonífojì* Ákórì,+ ó sì yí gba apá àríwá lọ sí Gílígálì,+ tó wà níwájú ibi tí wọ́n ń gbà gòkè ní Ádúmímù, ní gúúsù àfonífojì, ààlà náà dé ibi omi Ẹ́ń-ṣímẹ́ṣì,+ ó sì parí sí Ẹ́ń-rógélì.+
12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.