Nehemáyà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Apá tó tẹ̀ lé tiwọn ni Úsíélì ọmọ Háháyà, ọ̀kan lára àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà ti ṣe iṣẹ́ àtúnṣe, Hananáyà, ọ̀kan lára àwọn olùpo òróró ìpara,* ṣe iṣẹ́ àtúnṣe ní apá tó tẹ̀ lé tirẹ̀; wọ́n sì fi òkúta* tẹ́ ilẹ̀ Jerúsálẹ́mù títí dé Ògiri Fífẹ̀.+
8 Apá tó tẹ̀ lé tiwọn ni Úsíélì ọmọ Háháyà, ọ̀kan lára àwọn alágbẹ̀dẹ wúrà ti ṣe iṣẹ́ àtúnṣe, Hananáyà, ọ̀kan lára àwọn olùpo òróró ìpara,* ṣe iṣẹ́ àtúnṣe ní apá tó tẹ̀ lé tirẹ̀; wọ́n sì fi òkúta* tẹ́ ilẹ̀ Jerúsálẹ́mù títí dé Ògiri Fífẹ̀.+