ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 31:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 nígbà tí gbogbo Ísírẹ́lì bá wá síwájú Jèhófà+ Ọlọ́run rẹ ní ibi tó yàn, kí ẹ ka Òfin yìí sí gbogbo Ísírẹ́lì létí.+

  • Nehemáyà 8:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Torí náà, ní ọjọ́ kìíní oṣù keje,+ àlùfáà Ẹ́sírà mú ìwé Òfin náà wá síwájú àpéjọ*+ àwọn ọkùnrin àti àwọn obìnrin pẹ̀lú gbogbo àwọn tó lè lóye ohun tí wọ́n bá gbọ́. 3 Ó sì kà á sókè+ ní gbàgede ìlú tó wà níwájú Ẹnubodè Omi, láti àfẹ̀mọ́jú títí di ọ̀sán gangan, fún àwọn ọkùnrin àti àwọn obìnrin àti gbogbo àwọn tí ọ̀rọ̀ náà lè yé; gbogbo àwọn èèyàn náà sì fetí sílẹ̀ dáadáa+ sí ìwé Òfin náà.

  • Ìṣe 15:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Torí pé láti ìgbà láéláé ni Mósè ti ní àwọn tó ń wàásù nípa rẹ̀ láti ìlú dé ìlú, torí wọ́n ń ka ìwé rẹ̀ sókè nínú àwọn sínágọ́gù ní gbogbo sábáàtì.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́